OGUN OFA TODAJU
Oro agogo tutu pupo die, ogede omini pupa meta, odidi atare kan, gbogbo nkan inu pepeye . A o jo gbogbo eroja naa papo, a o lo ebu naa ti yoo kuna daada, a o da ebu naa sinu adin eyan fun 7days.
Leyin ojo keje, ki eni naa maa lo sibi kan lojumo.