Filter
Exclude
Time range
-
Near
BERU AWON ENIYAN MARUN. Bẹru Eniyan ti o juu ẹ lọ. Bẹru Eniyan ti o wa leyin e Bẹru Eniyan ti o ti ri tipetipe. Bẹru Eniyan ti o sese padé Bẹru Eniyan ti o mọ iwole ati ijade re
BERU OLORUN TORI OHUN MARUN YI. Beru Olorun nitori Oun lo da o. Beru Olorun nitori, Oun lo le se ohun gbogbo. Beru Olorun nitori, Aseyiowu ni Olorun. Beru Olorun nitori ko si Ara ti ko leè fi o da Bẹru Olorun nitori odo re lo máa pada si.
18
Oúnjẹ tí a kò bá jẹ rí, kìí dáni lọ́rùn. Translation The type of food one hasn't eaten before doesn't arouse one's appetite or cravings! Moral Familiarity breeds comfort! In everyday life, we tend to stick with what we know and feel comfortable with! This wisdom is applicable to habits, relationships, or decisions – sticking with what works unless there's a good reason to change. Gbógbó ijade ìwọ àti ẹbi rẹ nínú ọdun yi, ẹ kò ní jade le ikú l'ọwọ Laṣẹ Èdumare. ÀMÍN! A ku Ojúmọ́
31
ORIN DAFIDI 81:1-4 [1]KỌRIN soke si Ọlọrun, ipa wa: ẹ ho iho ayọ̀ si Ọlọrun Jakobu. [2]Ẹ mu orin mimọ́, ki ẹ si mu ìlu wa, duru didùn pẹlu ohun-elo orin mimọ́. [3]Ẹ fun ipè li oṣù titún, ni ìgbà ti a lana silẹ, li ọjọ ajọ wa ti o ni ironu. [4]Nitori eyi li aṣẹ fun Israeli, ati ofin Ọlọrun Jakobu. Jehovah jesu kiristi mayinkel mimo aye Raye olorun TI wa a dupe afiogo fun oruko yin oluwa gba ope emi mimo gba iyi loni oluwa gbogbo ibiti awon omo yin yio ma gba oluwa ewa ma bawon lo ogo ati olala ko leje ti won oluwa sebe mo gba ladura fun won ni gbogbo ona ti won yio gba oluwa ewa dide iranlowon fun won Anu yin ko fohun lorin won imole olorun ko ma to Sona won mo gba adura nibiti won rokan ore si oluwa ewa dide iranlowon fun won ewa gbe iranlowon yin dide fun won ema se fiwon sile abo oluwa kowa lorin aye won oluwa sebe ki imole olorun oba koma ton siona won mo rin won si inubu eje jesu eje jesu kiristi koma so leyin lorin tomo tomo ijade yin loni ati iwon le yin kole je ayo ogo ni fún jesu loke orun Hallelujah nioruko jesu kiristi oluwa ati oludade wa Amin
24
Jun 12
Replying to @justmeshhy
ijade la bich
1
25
ROMU 5:1-4 [1]NJẸ bi a si ti nda wa lare nipa igbagbọ́, awa ni alafia lọdọ Ọlọrun nipa Oluwa wa Jesu Kristi: [2]Nipasẹ ẹniti awa si ti ri ọ̀na gbà nipa igbagbọ́ si inu ore-ọfẹ yi ninu eyi ti awa gbé duro, awa si nyọ̀ ni ireti ogo Ọlọrun. [3]Kì si iṣe bẹ̃ nikan, ṣugbọn awa si nṣogo ninu wahalà pẹlu: bi a ti mọ̀ pe wahalà nṣiṣẹ sũru; [4]Ati sũru nṣiṣẹ iriri; ati iriri ni nṣiṣẹ ireti: Oju mo ire ati ayo ati alafiya ni oruko jesu ni agbara eje jesu oluwa mo dupe mo Fi ogo fun oruko yin oluwa gba ope wa ayeraye gba iyi wa Mo fi iriajo awon omo mi loni le eyin olorun oba lowon oluwa ewa gba gbogbo ogo ijade won ati iwon le won loni oluwa ewa ma bawon lo ayo towa ninu ojo oni je ko je ipi won ki alafiya jetiwon oluwa sebe imole yin to titon Sona won komase won okunkun Anu yin ko ma fohun Lorin aye won oluwa sebe loni ojo agbara oluwa wa gbe agbara re won won ki gbogbo ogo ki oleje ti eyin olorun oba beni korin koyin pada nioruko jesu kiristi oluwa ati oludade wa Amin
28
ORIN DAFIDI 30:1-4 [1]EMI o kokiki rẹ, Oluwa; nitori iwọ li o gbé mi leke, ti iwọ kò si jẹ ki awọn ọta mi ki ó yọ̀ mi. [2]Oluwa Ọlọrun mi, emi kigbe pè ọ, iwọ si ti mu mi lara da. [3]Oluwa, iwọ ti yọ ọkàn mi jade kuro ninu isa-okú: iwọ o si pa mi mọ́ lãye, ki emi ki o má ba lọ sinu iho. [4]Kọrin si Oluwa, ẹnyin enia rẹ̀ mimọ́, ki ẹ si ma dupẹ ni iranti ìwa-mimọ́ rẹ̀. Jehovah jesu kiristi mayinkel mimo aye Raye olorun ijile ife a dupe afiogo fun oruko yin nitori ti emuwa sun layo etu muwa rin imole alaye oluwa gba ope wa ilena ti timo loni gbogbo ijade awon omo mi ati iwon le won oluwa ewa ya si mimo ki e dide iranlowon yin fun won ki ewa ogo yin mabawon gbe oluwa sebe loni gbogbo ibiti won ma jade lo oluwa ewase afa ati omiga won ki Eda won si tile tile ki epawon mo ninu gbogbo iriajo won loni oluwa daku sebe ki imole ogo yin lematon si ona won mo rin won si inubu eje jesu eje jesu kiristi koma so lorin won ìbùkún oluwa ajejetan koma bawon gbe ki Anu oluwa ma fohun Lorin aye won oluwa sebe mo fi ijade won ati iwon le won le eyin olorun lowon oluwa ewa gba gbogbo ogo ki ayo ati igbala koleje ti eyin olorun nioruko jesu kiristi oluwa ati olugbala wa Amin Amin 🙏 loruko jesu
46
ijade dey sweet die na 40 days own i dey run currently. if i finish am, i go run go aos go rest
I hope you dey enjoy your Ijade
79
I hope you dey enjoy your Ijade
weather for what again? 😊
1
1
203
FTN ILI MAFIJA? AFERA: APSOLVENTSKO Drage kolege, roditelji, profesori i celokupna javnosti, Obraćamo vam se u trenutku kada je bezobzirnost, pohlepa i klasičan mafijaški šablon ponašanja takozvanih „zvaničnih predstavnika studenata“ dostigao svoj vrhunac. Danas, 10. juna, 500 studenata departmana E1 i E2 FTN-a trebalo je da proslavi završetak svog četvorogodišnjeg truda, rada i odricanja. Umesto svečanih odela, haljina i zaslužene proslave, dočekao nas je mrak. Bukvalan i metaforički. Apsolvetnsko veče kolega je OTKAZANO. Ali ne zbog tehničkih problema, već zato što su studentski parlament, aktuelni student prodekan, a po svemu sudeći i student prorektor zajedno sa bivšim studentom prodekanom, odlučili: „Ako mi nećemo strpati vaše pare u svoje džepove – nećete ni slaviti!“ Hronologija sabotaže: Kako radi studentska mafija? Svesni činjenice da godinama unazad večiti studenti i politički poltroni iz parlamenta zarađuju basnoslovne sume na naš račun, grupa studenata završnih godina odlučila je da preuzme stvar u svoje ruke. Želeli smo poštenu organizaciju, bez ugradnje i skrivenih troškova. Tada počinje progon: Pritisci i ucene (pre tri meseca): Čim se pokrenula tema organizacije, samozvani „predstavnici“ su vršili agresivan pritisak, tvrdeći da jedino oni i uprava fakulteta imaju „monopol“ na našu proslavu. Studenti su rekli jasno NE. Demokratskim glasanjem, ubedljivom većinom, izabrane su kolege van parlamenta da vode organizaciju apsolventske večeri. Prva sabotaža – Sala „Harmonija“: Organizatori pronalaze salu, dogovaraju sve detalje za 10. jun. Samo par dana kasnije, menadžer sale u strahu poziva i javlja kako im baš tada „najavljuju radove na elektromreži“. Slučajnost? Naravno da ne. Klasična politička sabotaža i pritisak odozgo. Tajna operacija „Ribarac“: Shvativši s kim imaju posla, organizatori u strogoj tajnosti, kako bi izbegli partijske pipke parlamentaraca, potpisuju ugovor sa restoranom „Ribarac“. U ugovor su ubačeni i amandmani koji striktno zabranjuju bilo kakvo političko oglašavanje u restoranu, što je naravno bez problema prihvaćeno. Izgledalo je da smo uspeli da se odbranimo od lešinara. Konačni udarac (9. jun – juče): Manje od 24 sata pre proslave, scenario se ponavlja. Menadžer „Ribarca“ očajan javlja, gle čuda, i njima je odjednom isključena struja! Gde idu vaše pare? Ovo nije priča o propisanoj proslavi. Ovo je priča o sistematskom reketiranju studenata. Kada su shvatili da 500 studenata ne želi da plati njihove „marže“ i finansira njihove privatne hirove, „večiti studenti“ iz fotelja su upotrebili sve svoje političke veze i poluge moći da ugase struju u privatnim objektima! Pitamo javno studentski parlament i studenta prodekana: Da li se preko krađe studentskog novca i ugradnje u apsolventske večeri, ekskurzije, "ijade" i konferencije kupuju nekretnine po Novom Sadu? Da li je to cena našeg četvorogodišnjeg školovanja, da budemo porez na luksuz nekolicini kupljenih diploma i večitih funkcionera? Nećemo ćutati! Ovo je direktan šamar svakom studentu koji je pošteno učio, svakom roditelju koji je odvajao od usta da plati školovanje, i svakom profesoru koji drži do integriteta ovog Fakulteta. FTN ne sme biti sinonim za mafiju, ucene i partijsko reketiranje. Ovim putem poručujemo i studentu prodekanu, i parlamentu, i prorektoru, kao i prethodnicima koji iz senke vuku konce: Saznaćemo ko je tačno i sa kojih pozicija moći zvao menadžere sala i pretio. Ovo nije kraj. Vaša bahatost je upravo probudila najveću snagu ovog fakulteta, same studente. Novac nam možete uzeti, proslavu možete pokvariti, ali obraz vam nećemo ostaviti.
45
533
2,386
40,655
ORIN DAFIDI 29:1-4 [1]Ẹ FI fun Oluwa, ẹnyin ọmọ awọn alagbara, ẹ fi ogo ati agbara fun Oluwa. [2]Ẹ fi ogo fun Oluwa, ti o yẹ fun orukọ rẹ̀; ẹ ma sìn Oluwa ninu ẹwà ìwa-mimọ́. [3]Ohùn Oluwa mbẹ lori omi pupọ̀: Ọlọrun ogo nsán ãrá: Oluwa mbẹ lori omi pupọ̀. [4]Ohùn Oluwa li agbara; ohùn Oluwa ni ọlánla. E Karo eyin oko mi se alafiya ni eji oluwa olorun alafiya yio ma wa pelu yin mo gba adura fun yin lowuro yin nitori dida to dayin si opayin mo oluwa adupe nitori ore yin loriwa ese baba mi ogo ola iyi ni fún oruko yin oluwa ese mo wa Fi iriajo awon omo mi loni le eyin olorun oba lowon oluwa ewa gba gbogbo ogo ewa ma bawon lo loni ojo Anu jeki Anu yin wa won rin bi won tise jade lo loni ijade won ati iwon le oluwa ewa ya si mimo ki ijade won ko ma se mu ewudani mo gba adura fun won loni gbogbo ese ti owu ki won lese oluwa ewadarini won ki eyawon si mimo oluwa daku sebe ki epa ona mo fun won mo gba ladura fun won gbogbo ohun to tosi won oluwa ewase fun won ki emu inuwon du ki emu ayo won ku oluwa sebe emi mimo sebe mo rinwon si inubu eje jesu eje jesu kiristi komaso lorin won oluwa sebe ki ìbùkún orun kole tiwon beni korin kiwon jade lo kiwon le layo ki ewase ohun tuntun ninu aye won beni korin nioruko jesu kiristi oluwa wa Amin
20
Replying to @keonhositoo
ijade perra yome la creí
1
672
Replying to @UkuleleOtter
Nije zbog lajka,a lajkujem sve koje pratim i ne pratim,sta mi se dopadne.imam kao tri ijade pratilaca,a vidim samo 20. 🤔
2
26
ORIN DAFIDI 27:1-4 [1]OLUWA ni imọlẹ mi ati igbala mi; tali emi o bẹ̀ru? Oluwa li agbara ẹmi mi; aiya tali yio fò mi? [2]Nigbati awọn enia buburu, ani awọn ọta mi ati awọn abinuku mi sunmọ mi lati jẹ ẹran ara mi, nwọn kọsẹ, nwọn si ṣubu. [3]Bi ogun tilẹ dótì mi, aiya mi kì yio fò: bi ogun tilẹ dide si mi, ninu eyi li ọkàn mi yio le. [4]Ohun kan li emi ntọrọ li ọdọ Oluwa, on na li emi o ma wakiri: ki emi ki o le ma gbe inu ile Oluwa li ọjọ aiye mi gbogbo, ki emi ki o le ma wò ẹwà Oluwa, ki emi ki o si ma fi inu-didùn wò tempili rẹ̀. E Karo eyin oko mi se alafiya ni eji ekun odun awon eso ano oluwa yio bami da won si nioruko jesu ema jere won oluwa yio wa pelu yin nioruko jesu mi oni wa yin ti emase opolopo odun laye ati alafiya Jehovah jesu kiristi mayinkel mimo apata aye Raye olorun ijile ife mo gbe yin ga mo se yin loba oluwa gba gbogbo ogo mo gba adura fun yin ninu ose tuntun yin oluwa yio dide iranlowon fun yin okan yio bale imisi olorun yio ma bayin gbe bi etise jade lo ninu ose yin oluwa yio ma fi isore so yin eje jesu yio ma se amona yin mo gba ladura funyin loni ijade yin Koni bi araye ninu iladabo yin ayo lomaje oluwa yio mi imiye siyin omadara funyin Anu yio wa yin rin ki ejade lo layo ki epada bo pelu ekurere ìbùkún oluwa daku sebe ni oruko jesu oluwa yio da awon omo na si fun yin mo gba adura fun yin ninu ose yin oluwa yio bukun fun yin oluwa yio wa pelu yin nioruko jesu kiristi oluwa wa Amin Amin loruko jesu 🙏
43
Replying to @olanikemi
Yi o si busi fun mi Iwole ati ijade mi Ire ni yio ma je oo AMIN JESU
2
i genuinely used to have voices and then one day they just fuckign disappeared. did i tlel them to shut the fuck up too much or something. can they come back nwo . i msorry feebie im sorry ijade im sorry pls come back nwo i feel so lonely my brain is rotting i dont know how to th
1
47
ifa oji re orumila oji re….ijade wa iwole wa koni ni bi omo araye ninu o
1
3
43
Meet Veteran Nigerian Female Journalist, Mrs Funke Egbemode. She was former President, Nigerian Guild of Editors, former Managing Director of New Telegraph Newspaper and former Commissioner for Information and Orientation in Osun State. The Veteran Journalist is a native of Ijade in Osun State. Wishing her more years of service to her Fatherland.
1
2
18
740
Replying to @Letter_to_Jack
7 days for female 9 days for male 14 days for twins and multiple. 41 days ijade Omo. What they taught us in Yoruba class.
3
7
32
2,188
I swear you no go escape the suing this time 😂😂😂😂 You don see them teb***h shoe before the ones way dey go ijade 😂
Maths teacher 😂
1
2
94
Loni Ojo Aje Ijade wa Kororun, Ise wa ko mu Ere wa, A o ni ba Were wo oko 🚙 po Ooo...Ire ni Tiwa 🙏
16
18
32
444