Awon ona mefa wonyi ni afi le dekun aisan yi,
Fifo owo lera lera toni toni pelu ose laabe omi ti on yo, o kere ju fun aaya ogun. Ti ose ati omi ko ba si, a le lo ose imudara ti a ti se si inu ike lati fo owo wa.
(Covid-19 Yoruba)
#Covid19
#Covid19LL
#staysafe